0 Views· 10/05/24· Music

ASAKE - FUJI VIBE (LYRICS)


Pumba
17 Subscribers

@ASAKEMUSIC
Fuji vibe lyrics video

[Intro]
Ololade mi Asake
O ti po gan
Gan, gan, gan
Tune into the king of sound and blues
[Verse 1]
Ẹ ma f'agili ti wọ bọ o, kẹ ma fi were we mi
Ẹni ba lọ lo le mọ, a bo le s'alaye ni
Awọn ọmọ better ti pọ
Keep your money tan ba n bọ
Lokeloke la ma lọ
Ẹ ri pe Balenciaga yẹn yatọ
Baby wa uhn uhn
Mi o raye k'eeyan f'ẹran kan jeun
Oje lo jẹ uhn uhn
Ko n ṣe iwo nikan ẹgbẹ ẹgbẹrun
[Chorus]
Haba!
Vanessa ẹ bẹrẹ mu kẹ gboju
Ye, it's a mental
O l'owo o lọ n loyun
Ah sukerike rike, bumbum
Ẹ dẹ maa jo gan-an o di dandan
Super extravagance l'ọmọ
Emi l'Asake mẹdo ta n sọ
Baby you catch my feelings ahn ahn
I'm getting weaker
You dey shack my head like gbana
This your booty, are you from Ghana?
Ọmọ olo make ka ma nawọ ya, ma se jẹ kan mọ
This your booty fit to jawaya, o ga de sanmọ
Ibadi yẹn fẹ ki n se wire into your aza
Ọmọ olo mi, ye ma gaza (Gaza)
[Verse 2]
No pressure, wọn da mọ
Ọga Ade ẹni lọ lo bọ
Wọ America lọ fun tour
Akata wọn pọlọpọ
Plenty plenty ọmọge
Wọn fẹ jẹ kin sa nile
Ori mi lo yọ mi, ọta iba yọ mi
Ọmọ ọpẹ I dey find my way
Make bad belle no come stop my reign
Bẹbẹ n lọ like a moving train
Fun mi ni big big money no chicken change
Owo n bọ, ọla n bọ, alaafia ati igbadun n bọ
I no wan talk plenty talk, my record can back it up
La-do-re-mi-fa-mi-so-la (L'Eko)
Oluwa ni s'ọla
Yarinya
[Chorus]
Haba!
Vanessa, ẹ bẹrẹ mu kẹ gboju
Ye, it's a mental
O l'owo o lọ n loyun
Ah sukerike rike, bumbum
Ẹ dẹ maa jo gan-an o di dandan
Super extravagance l'ọmọ
Emi l'Asake mẹdo ta n sọ
Baby you catch my feelings ahn ahn
I'm getting weaker
You dey shack my head like gbana
This your booty, are you from Ghana?
Ọmọ olo make ka ma nawọ ya, ma se jẹ kan mọ
This your booty fit to jawaya, o ga de sanmọ
Ibadi yẹn fẹ ki n se wire into your aza
Ọmọ olo mi, ye ma gaza (Gaza)
[Outro]
Mr Money (Money dance)
Money (Money dance)
Money (Money dance)
Money (Money dance)

Show more

Up next


0 Comments